Question Options Answer
YORUBA JSS 1: Labẹ igi orombo ti o wa lẹba igi agbalumọ ni Tọla, Yẹmi ati Kemi ti n ṣe ere bojuboju. Ere okoto tita ni won kọkọ ṣe ṣugbọn ere okun mẹran ni won fẹ ṣe ti Iya won Amina fi de lati ọja Ifọ. Awon ọmọde wonyii ṣere idaraya ti won n ṣe ti lati lọ ki Iya won kaaba. Inu Iya won dun nitori pe awon ọmọ naa ti pari isẹ ile ti o yan fun ọkọọkan wọn. O mu ileri rẹ ṣẹ nipa fifun awọn ọmọ naa ni nnkan abọ ti o ra fun wọn. Inu wọn dun, Tọla ati Yemi dọbalẹ nigba ti Kẹmi kunlẹ. Awon ọmọ naa A) agbalumọ
B) ọsan
C) rọba
D) kaṣu
optionA
Ere idaraya ti awon ọmọ naa kọkọ ṣe ni ere _____ A) okoro tita
B) bojujboju
C) okun meran
D) ludo
optionB
Ere idaraya ti won fẹ ṣe nigba ti Amina de ni A) bojuboju
B) okun meran
C) okoto tita
D) ayo ọlọpọn
optionB
_____ ni Iya awon omo naa A) Tola
B) Kemi
C) Amina
D) Yemi
optionC
Ki ni idi ti inu Iya awon omo naa se dun si won? A) wọn ṣe iṣẹ ile
B) won se ere idaraya
C) won n ja
D) won wa labẹ igi orombo
optionA
Ọrọ orukọ ti a ko ṣẹda ni A) ọlọ
B) ijokoo
C) aja
D) ounjẹ
optionC
Orisii Litireso meloo ni o wa? A) ikan
B) meji
C) meta
D) merin
optionB
Oro oruko ti a seda nipa afomọ aarin ni A) oṣooṣu
B) ọsọọsẹ
C) ọmọkọmọ
D) iyaale
optionA
Ewi alohun ajẹmayẹyẹ ni A) Orin oro
B) ẹrẹ ifa
C) Ogun pipe
D) bọlọjọ
optionD
Litireso wulo fun A) idaraya
B) orin
C) ijo
D) orun sisun
optionA
'45' ni ede Yoruba ni A) aarunlelogorun
B) eerindinlogoji
C) aarunlelogoji
D) eerindin laadọta
optionC
Ọrọ orukọ ti a ṣẹda ni A) igbalẹ
B) orin
C) iwe
D) baba
optionA
A ṣẹda "alaṣọ" nipa lilo A) afomọ ẹyin
B) afomọ aarin
C) apetunpe
D) afomọ ibẹrẹ 'oni'
optionD
"Ẹẹtalelọgbọn" jẹ A) 43
B) 33
C) 23
D) 53
optionB
A ṣẹda "ọmọkọmọ" nipa lilo A) apetunpe
B) afomọ aarin
C) afomọ iwaju
D) afomọ ẹyin
optionB
Ilu to n lo "Dadakuada" ni A) Ọyọ
B) Egba
C) Ẹgbado
D) Ilorin
optionD
Awọn ______ lo n sun Iyẹrẹ A) babalawo
B) ọlọya
C) eleṣu
D) oloro
optionA
"Noun" ni ede Yoruba ni A) ọrọ orukọ
B) ọrọ iṣe
C) ọrọ apọnle
D) asopọ
optionA
"Verb" ni ede Yoruba ni A) ọrọ orukọ
B) ọrọ iṣe
C) ọrọ aponle
D) ete onise
optionB
Ọrọ orukọ aṣeeka ni A) iyẹpẹ
B) elubọ
C) omi
D) tabili
optionD
JSS TWO YORUBA: Ni ọjọ kan, Funke wa ni ile epo nibi ti o ti n sise yii, ti o si n ta epi fun awon onimọto ni ọkọkan, ejeeji. Ni ojiji ni awon igaraọlọṣa t'awọn ti ibọn lọwọ ya wọ ile epo ibi ti Funkẹ ti n ṣiṣẹ. Afi Kosa!, kosa! kosa! ti wọn da ibọn bolẹ. Ọrọ do boolọ o pagoda lọna. Gbogbo awọn ti wọn paaki lati ra epo bẹ silẹ ninu mọto, wọn si n salọ, lati sa asala fun ẹmi wọn. Mo n gbọ "Doju ẹ delẹ, doju e delẹ" bẹẹ ni wọn n yin ibọn soke kosa kosa. Logan ni awọn eniyan bii mẹfa ti fara gba A) awon ota wa
B) awon ole wa
C) awon olopa wa
D) awon olukowa
optionA
Ki ni awon onibara ti won gbo iro ibon se? A) won sa fun emi ara won
B) won dojuko awon ole na
C) won gba ibon lowo awon ole
D) won salo si odo awon olopa
optionA
Ki lo sele si awon meta ti won ku? A) ota ibon ba won
B) aja ke won je
C) omi pa won
D) ijamba ina lo pa won
optionA
Ki ni idi ti won fi ta Funke ni kokosẹ? A) n lọ tikọtikọ
B) o mbe awon ole na
C) o feran won lopolopo
D) ko mo ouhn to nsele
optionA
Awon wo ni won gba owo lọwọ awon eniyan? A) funke
B) onibara
C) ile epo
D) ole
optionD
Awon wo ni won n kigbe ole, ole, oleee nigba ti awon ole lọ tan? A) awon olopa
B) funke
C) awon eniyan ile epo
D) atedanti
optionC
Igbe wo ni Funke n ke nigba ti o wa ninu ẹjẹ ara rẹ? A) e jowo e bami pa awon ole yi
B) ẹ jọwọ, ẹgba mi o, e ma je n ku bayii
C) e jowo e bami gba owo mi
D) e jowo e bami mu won
optionB
Igbe wo ni awon ole pa bi won ti wọ ile epo? A) e jade sita eyin eniyan
B) e wa bami ja
C) e doju bole
D) e tan epo fun wa
optionC
Orukọ miiran ti won pe "awon ole" ninu ayoka oke ni A) funke
B) igaraolosa
C) olopa
D) atedanti
optionB
Bawo ni ibon awon ole se n fun? A) kosa kosa
B) koya koya
C) kosekose
D) kolokolo
optionA
Awon ilu to maa n kọ OBITUN ni A) Ọyọ
B) Ekiti
C) Egba
D) Ondo
optionA
______ lo maa n ṣiwaju ijo A) Orin
B) Ẹkun
C) Ilu
D) Ayọ
optionB
Awon ______ lo maa n sun IYẸRẸ A) eleegun
B) onifa
C) eleṣu
D) oniwaasu
optionB
______ jẹ apẹrẹ ijo ibile A) Hip-hop
B) Makosa
C) Bata
D) yahuse
optionC
__ je a)Isare ajemẹsin A) ijala
B) babalawo
C) Ogun
D) Orin
optionA
Awon Ilorin lo ni A) ifa
B) obeke
C) Ṣẹwẹlẹ
D) Olofa
optionC
80 ni ede Yoruba A) ọgọfa
B) ọgọrin
C) ọgọjọ
D) aadọrin
optionB
Ayẹyẹ ti won maa n se ni ilẹ Yoruba ni A) akara oyinbo
B) kọọtu
C) ẹrin
D) igbeyawo
optionD
Awon ______ lo maa n sere bojuboju A) ọmọde
B) ọkunrin
C) obinrin
D) arugbo
optionA
Awon ẸGBA lo n kọ A) ijala
B) ege
C) iyere
D) Orin oro
optionB
JSS THREE YORUBA: Ni abule Ipake lẹba Igbogun, awon ore meta kan wa: Ajani, Eyinafe ati Taofeek. Ise agbe ni won n se. Oko won ko si jina sira. Ni ojo kan, Taofeek lo si Ile Ajani ni oke oko, won ki ara won, o si so fun Ajani pe oun fe ya awon agbado oko oun tori pe won ti gbo, o te siwaju pe oun fe lo ta won ni ọja Ifọ ki oun le ri owo idanwo BECE Kafaya, omo oun san. Bi inu ti ri lobi n yan, Ajani da Taofeek lohun. O sọ pe oun alara fẹ wa si ile re lati wa so fun-un pe oun fero oko o A) Ipake
B) Igbogun
C) Ibogun
D) Ifo
optionC
'O' ti won fala si ninu ayọka oke duro fun A) Ipake
B) Ajani
C) Eyinafe
D) Taofeek
optionD
Ta lo fe yẹ ona si oko re? A) Taofeek
B) Ajani
C) Eyinafe
D) Ko si
optionC
Kini idi ti Taofeek se fe lọ ta agabdo re? Lati __ A) fi ra nnkan loja
B) fi ran Kafaya nile iwe
C) fi jeun
D) san owo idanwo
optionD
Iruse asa wo lo suyọ ninu ayọka oke? Aṣa A) iranraẹnilọwọ
B) ikomọjade
C) ọmọ titọ
D) iṣẹ ṣiṣe
optionA
Orukọ miiran ti owo ṣiṣe n jẹ ni A) katakata
B) oja tita
C) ipolowo oja
D) ipolongo
optionA
Faweli iwaju ni A) o
B) a
C) i
D) u
optionC
Oja ti awon Yoruba maa n polowo pe "Ye ọbẹ! ni A) eja
B) eran
C) igi
D) adie
optionB
Orukọ ti won maa n pe obinrin ti ko rọmọbi ni ile Yoruba ni A) abiamọ
B) abiye
C) Abirun
D) agan
optionD
Fawelo aarin ni A) a
B) ọ
C) u
D) I
optionA
Feweli meloo lo wa ninu ede Yoruba? A) mewaa
B) mejila
C) meji
D) mẹjọ
optionB
_____ lo maa n rọ ọkọ ati ada A) Alagbẹdẹ
B) Gbẹnagbẹna
C) Agbẹ
D) Ọdẹ
optionB
Ọrọ orukọ ni ede Geesi ni A) name
B) noun
C) pronoun
D) proper
optionB
Igbesẹ akọkọ ninu itọju alaboyun ni ode oni ni A) yiya aworan oyun
B) ayewo eje
C) Fifi orukọ sile nile iwosan
D) kiko eru omo lo si Ile owosan
optionD
Ọmọ o ni agbara lati wa si aye ati lati ku ni iye igba ti o wuu ni awon Yoruba n pe ni A) Abiku
B) Awaye
C) Abaya
D) Abiye
optionA
____ ni won fi n tọju alaboyun ni atijọ A) egbogi
B) abẹrẹ
C) omi
D) agbo
optionA
85 ni ede Yoruba ni A) aarun din lọgọrin
B) aarunlelogorin
C) eejolelaarun
D) aarunlenigba
optionB
Awon to n ta ọja pẹpẹpẹ bii bisikiiti, suuti ni won n pe ni A) oniworobo
B) alarobọ
C) ope
D) karakata
optionA
Awon to n ta ọja oko ni won n pe ki A) ara oko
B) oloko
C) oniwosiwosi
D) alaroobọ
optionD
____ le fa airomobi A) ijo jupajupa
B) arun
C) orin
D) ise sise
optionA
JSS ONE YORUBA: Ogundele feran aja re pupọ. Bi aja yii see n pẹtu lo n podu ọya, bee ni o n pa agbonrin to se iwo lori Sarasota. Bi Ogundele ba ti n lọ dẹgbẹ, kii fi aja re silẹ tori oun lo maa n rugbo ti așiri awon ẹran fi n tu, ti Ogundele si n raye pa won. A) Oniṣowo
B) Akọwe
C) Ọdẹ
D) Olounjẹ
optionC
Egberun mejo naira ni Ogundele n ta A) Odu oya
B) Ehoro
C) Agbonrin
D) Ikun
optionA
Ewo ni owo re pọ ju ninu awon eran ti Ogundele pa? A) Ikun
B) Agbonrin
C) Ọya
D) Aja
optionB
Eranko abiwo ni A) Agbonrin
B) Ikun
C) Oya
D) okete
optionA
A le pe Ogundele ni ọdẹ A) Alaja-nibọn
B) Etile
C) Agbonrin
D) Ẹtu
optionB
Awon eran ______ ni Ogundele ta ni egberun meji tabi meta A) Kekere
B) nla nla
C) eran
D) gbogbo eran
optionA
_____ ni alabasise po Ogundele A) Ikun
B) Ọmọ
C) Ọrọ
D) Aja
optionD
Ta ni o maa n tu asiei awon eran? A) Ibon
B) Ẹtu
C) Aja
D) Agbonrin
optionC
Ki ni Ogundele fi n pa ẹran? A) Pampẹ
B) Waya
C) Ọkọ
D) Ibon
optionD
Egberun meedogun ni Ogundele ta _____ A) Eku
B) Ẹtu
C) Agbonrin
D) Ẹyẹ
optionC
50 ni onka Yoruba ni _____ A) Aadoje
B) Aadorin
C) Aadorun-un
D) Aadota
optionD
Meloo ni alifabeti Yoruba? A) Meedogun
B) Meedogbon
C) Mejidinlogbon
D) Mejidinlogun
optionB
Orisii faweli meloo ni owa? A) Meje
B) Meji
C) Meta
D) Merin
optionB
______ ni akọbi Ọkanbi A) Oduduwa
B) Lamurudu
C) Oranmiyan
D) Olowu
optionC
Awon wonyi ni ohun elo idana ayafi ______ A) Ata rodo
B) Obi
C) Orogbo
D) Iyọ
optionA
_____ lo le so tọkọtaya pọ ninu igbeyawo ode oni A) Obi
B) Imaamu
C) Olukọ
D) Dokita
optionB
Faweli aranmupe ni A) a
B) s
C) in
D) u
optionC
Egba lo ni ege, ilu to maa n kọ Obitun A) Ondo
B) Egba
C) Dadakuada
D) Babalawo
optionA
Oye oba Ẹgba ni A) Elekoo
B) Ọlọwọ
C) Akire
D) Alake
optionD
_____ ọjọ ni Oduduwa fi rin lati Mẹka de Ifẹ A) Oodunrun-un
B) Aadorun-un
C) Aadọta
D) Oodunta
optionB
Consonanti meloo ni o wa ni ede Yoruba ______ A) Mejidinlogun
B) Ogun
C) Adọrin
D) Mẹẹdọgbọn
optionA
Iwe mimọ ti awọn musulumi n lo ni ______ A) Bibeli
B) Opon ifa
C) Alaroye
D) Qurani
optionD
Iro ti a pe ti ko si idiwọ fun eemi ni ______ A) Fawẹli
B) Consonanti
C) Aranmupe
D) Airanmupe
optionA
29 ni onka Yoruba ni _____ A) Okanlelogun
B) Okandinlogbon
C) Okanlelọgbọn
D) Esandinlogbon
optionB
Ounjẹ ilẹ Yoruba ni ______ A) Amala
B) Apu
C) Kunnu
D) Indomi
optionA
Ipinlẹ meloo lo wa lorile ede Naijiria A) Ėrindinlogun
B) Ẹrindinlogbon
C) Efalelogbon
D) Ẹrindinlogoji
optionD
oriṣi igbeyawo meloo lo wa A) Ikan
B) Meji
C) Mẹta
D) Mẹrin
optionB
Ewo ni ko bẹgbẹmu A) Kwara
B) Eko
C) Lọkọja
D) Ogun
optionC
Ẹsin ______ ni wọn ṣe ni ilu mẹka ni atijọ A) Ibọriṣa
B) Kirisitẹni
C) Musulumi
D) Bhuda
optionD
Awọn ti o ni ijala ni ______ A) Ọlọdė
B) Babalawo
C) Ọlọya
D) Ọlọṣun
optionA
Ọjọ meloo lo wa ninu ọsẹ? A) Mẹwaa
B) Mẹjọ
C) Mẹfa
D) Meje
optionD
_____ ni ṣẹda ohun gbogbo A) Ẹrọ Kọmputa
B) Olodumare
C) Eniyan
D) Onimọ sayẹnṣi
optionB
Oṣu meloo lo wa ninu ọdun? A) Mẹwaa
B) Mọkanla
C) Mejila
D) Mẹtala
optionC
Oṣu ti o keyin ninu odun la n pe ni A) Erele
B) Beelu
C) Ọpẹ
D) Ẹrẹna
optionC
Kini Arunlelaadọta ni figọ A) 55
B) 56
C) 57
D) 58
optionA
Igbeyawo wa fun _____ ati _____? A) Ọmọdekunrin ati ơmọdebinrin
B) Ọdọmọkunrin ati ọdọmọbinrin
C) Ọkunrin ati Ọkunrin
D) Obinrin ati obinrin
optionB
Fawẹli ti o kẹyin ninu aranmupe ni A) An
B) In
C) Ẹn
D) Un
optionD
Meloo ni Fawẹli aranmupe? A) Meji
B) Mẹta
C) Mẹrin
D) Marun-un
optionD
Awọn ẹlẹsin to ma n pe ẹsa ni awọn _____? A) Eleegun
B) Ọlọya
C) Onisango
D) Ọlọbatala
optionA
Orisii ewi alohun meloo ni o wa? A) Mẹrin
B) Mẹta
C) Meji
D) Marun-un
optionC
YORUBA JSS TWO Oriki se pataki ninu asa Yoruba. Oriki je awon oro iquri. Yoruba maa n fi yin tabi pon ara won tabi pon ara won tabi eni ti inu won ba dun si. A) Aarọ kutu
B) Afẹmọju
C) Gbogbo igba
D) Irọlẹ
optionC
Ojo keloo ni a n so omo lorulo ni ile Yoruba? A) Ojo kesan-an
B) Kejo
C) Mejila
D) Kerin
optionB
Yoruba n fi oriki ______ A) Yin ara won
B) Pa ara won
C) Ja ogun
D) Ṣe oge
optionA
Orisii oeiki meloo ni alakaye sọ ninu akaye re? A) Marun-un
B) Mefa
C) Mejọ
D) Mejila
optionA
Ki ni oriki jẹ fun ẹni ti a n ki? A) Idalẹbi
B) Iwuri
C) Ironu
D) Ekun sisun
optionB
Gẹgẹ bi ayoka ti lọ, ohun ti o se pataki fun Yoruba ni A) Oriki
B) Ija
C) Aso wiwo
D) Oge sise
optionA
Lara awon ti oriki wa fun ni A) Afoju
B) Arọ
C) Bọrọkini
D) Amutơrunwa
optionC
Ki ni oriki maa n hu jade lara omode? A) Igbe nla
B) Igbẹ
C) Ẹrin musẹ
D) Aagun
optionC
Ki ni alakaye fi gbagbo pe omo ikooko maa n igboro? A) Oriki
B) Orin
C) Ariwo
D) Didakẹ
optionA
Akọle wo ni o ba ayọka oke yii mu? A) Oriki
B) Pataki oriki ni ile Yoruba
C) Orisiirisii oriki
D) Oriki oruko
optionB
Meloo ni alifabeti Yoruba? A) Meedogun
B) Meedogbon
C) Mejidinlogbon
D) Mejidinlogun
optionB
Orisii faweli meloo lo wa? A) Mẹrin
B) Mẹta
C) Meji
D) Eyọkan
optionC
Ewo ni ko bẹgbẹmu A) Ibadan
B) Ọyọ
C) Lẹki
D) Ọṣun
optionC
---- le so tokotaya pọ ninu igbeyawo ode oni A) Babalawo
B) Olukọ
C) Imaamu
D) Sango
optionC
Irufẹ asa iranra-eni-lowo ti o je pe ise ni won fi n san ise pada ni A) Ẹbẹsẹ
B) Aaro
C) Ọwẹ
D) Eesu
optionB
99 ni ede Yoruba ni A) Ookan-le-loodunrin
B) Eerindinlogoji
C) Eesandinlogojọ
D) Ookandinlọgọrun-un
optionD
Jijẹ-mimu ni won fi n san _____ pada A) Aaro
B) Ọwẹ
C) Arokodoko
D) Ẹbẹsẹ
optionB
Awon _____ lo maa n sun IYẸRẸ A) Ọdẹ
B) Ọlọya
C) Eleegun
D) Babalawo
optionA
Alọ ti o ni Orin ninu ni alo ______ A) Apagbe
B) Apamọ
C) Onitan
D) Ijapa
optionA
Irufẹ asa iranra-eni-lowo ti won ti n fi owo ran ara won lọwọ ni A) Ẹbẹsẹ
B) Ajọ
C) Aaro
D) Arokodoko
optionB
40×2 a fun wa ni A) Ogoji
B) Ejilelogoji
C) Erinlelọgọjọ
D) Ọgọrin
optionD
Igbesẹ kẹta ninu igbeyawo abinibi ni A) Alarina
B) Ifojusode
C) Iwadii
D) Idana
optionD
Okan lara ohun elo idana ni ______ A) Ata
B) Gaari
C) Ọdunkun
D) Oyin
optionD
Ọmọ ti Iya re o ṣe nnkan oṣu ti won fi bii ni A) Taye
B) Ilọri
C) Ige
D) Ọkẹ
optionB
Ohun elo isomoloruko ti o duro fun JIJẸ AYE PẸ ni A) Omi
B) Owo
C) Iru
D) Epo
optionB
Oruko abisọ ni A) Abiọdun
B) Ajayi
C) Akankẹ
D) Aja
optionD
Ẹbun pataki ti won maa n fun obi ọmọbinrin ti ọkọ rẹ ba nile ni A) Ẹkun agbe omi
B) Ogere epo
C) Ẹkun agbe ẹmu
D) Ekufọ agbe
optionC
Ọjọ keloo ni wọn n sọmọlorukọ ni ode oni? A) Ikẹjọ
B) Ikeje
C) Ikẹfa
D) Ikarun-un
optionA
Ewo ni ko bẹgbẹmu? A) F
B) W
C) N
D) Ẹ
optionD
Awon ọlọde lo maa n A) Sun rara
B) Sun ijala
C) Sun ekun iyawo
D) Sun ẹkun ọmọde
optionB
Ọmọ ti o ni ika ọwọ mefa ni won n pe ni _______ A) Olugbodi
B) Ibadi aran
C) Sango tade
D) Fayemi
optionA
Orukọ inagije ni A) Ajayi
B) Bamidele
C) Eyinafẹ
D) Jimoh
optionD
Ewo ni ko begbemu? A) Iru
B) Epo
C) Omi
D) Ororo
optionD
34 Idile to n jẹ AYANWALE ni A) Onilu
B) Eleegun
C) Onigbajamọ
D) Oloro
optionA
Ọjọ meloo lo wa ninu ọsẹ? A) Merin
B) Marun-un
C) Mẹfa
D) Meje
optionD
Osu meloo lo wa ninu ọdun A) Mẹsan
B) Mẹwaa
C) Mejile
D) Mejila
optionC
Ogun le fa ______? A) Ibukun
B) Ifẹmiṣofo
C) Ayọ
D) Ire
optionB
Awọn Yoruba le lo _______ lati fi ja ogun A) Ida
B) Iṣo
C) Ewe
D) Iwe
optionA
Igi owo ni ________ A) Igi ewedu
B) Igi Ata
C) Igi rọba
D) Igi agatu
optionC
Ipinlẹ ______ lo wa ni orilẹ ede naijiria A) Mẹrinlelọgbon
B) Mẹrindinlọgbọn
C) Mẹfalelọgbon
D) Mẹfadinlọgbọn
optionB